O wu mi ki nma fi agbari mi ronu ti mba ji loju orun. Mo fe ki nji says Ron ala ti mo la loju orun. Ise opolo wu mi ju ise ara lo. Sugbon, kilo de ti awon omo Adamo o fe sango fun ise opolo? Kilode ti awon omo araye fe pe ise idoti bi "payunyun" oko wiwa fokunrin, "gbeyagbeya" fun obinrin lomo araye fe. Eniyan bi aparo lomo araye nfe. Olorun jowo ko wa yo ninu ogun omo araye. Yoruba o da, Yoruba o da. Ki Olorun gbe wa pade awon eniyan alalubarika, eniyan rere, oluranwo.