Ni mimu akori yi wa si opin, nje o ti wa n ye o bayi ore mi pe...iwulo ahon wa ti ga julo ni lati fi royin ihinrere ti o ri ninu Jesu Kristi......ranti pe iwe owe 18:21 so pe; " iku ati iye nbe ni ipa ahon: awon eni ti o ba si n lo yoo je ere re"....bawo lo ti n lo tire??🤔🤔