Ariwo ayo, ijo ati orin naa ni ipa ti o po l'ati ko nigba ti a ba n yin Olorun. Apere eyi wa ni inu iwe 2 Samuel 6:14-16.....A mo Dafidi oba si eni bi okan Olorun nitoripe o mo ona ti a le gba de okan Olorun pelu fi fi ojulowo ope ati iyin ti o lagbara fun un....🎷🎷💃💃💃