Gege bi awon wooli igbaani ti fi Olorun se atona won ninu ohun gbogbo naa ni awon aposteli ti tesiwaju lati maa se koda l'ehin iku ati ajinde Jesu. Ise awon aposteli ori kewa ati ikokanla(Acts 10&11) so fun wa bi emi Olorun ti to, ti o si dari Korneliu ati Peteru....ba wa kalo 👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻.....