Okunrin kan wa ti a o ko nipa re, sugbon ki a to kan oran re; a gbodo fi idi awon okodoro kan mule ki a le mo ohun ti o fa a ti o fi gbe igbese re naa ti o gbe. Eyi ni yoo mu wa lo ka iwe awon oba keji; ori kaarun(2 Kings 5:1-3, 9-11, 13-16)......👩💻👨💻👩💻👨💻👩💻👨💻