Bi o ba je pe o ba ko eko yi ni ose ti o koja, jowo ri daju wipe o d'arapo mo wa l'ati ko apa keji re sugbon bi bee ko, se daadaa l'ati koko lo gbo apa kini, ki o to gbo apa keji tori ase ni Emi Mimo pa fun wa l'ati tun eko naa ko l'eyin odun kan ti akoko ko o.....ki Olorun ki o bukun yin....Amin....