Listen

Description

A kú àsìkò yí ooo

Ìtàn ọmọ Nàìjíríà la tún mú tọ̀ yín wá. A ti ń sọ̀rọ̀ nípa Ìfẹ̀onúhàn láti bíi ọ̀sẹ̀ mélòó kan.

Ǹjẹ́ ẹ ti gbọ́ nípa 1897? Tí ẹ bá fẹ́ mọ bí ìtàn Ìfẹ̀onúhàn ṣe bẹ̀rẹ̀, ẹ ní láti mọ iṣẹlẹ ọdún ùn 1897.

Ìtàn alágbára la tún mú tọ̀ yín wá.