Listen

Description

Ẹ̀sìn àti Nàìjíríà

Ẹ kú dédé àsìkò yìí. Ìtàn ọmọ Nàìjíríà la tún mú wá. Ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn kò ṣé fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn. Gbogbo wa la rí bí ètò ẹ̀kọ́, ìlera, àbò àti ẹ̀ka tó kù. Kí wá ni ohun tí  ó yẹ kí àwọn adarí ẹ̀sìn wá ṣe láti fi kún ádùrá ni orílẹ̀-èdè wa?

Láti gbọ́ ètò tòní ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́