Listen

Description

Koko Ise : Asa Iranra-eni-lowo: Asa Iranra-eni-lowo je asa ti o gbajumo laarin awon Yoruba ni aye atijo.

Asa Iranra-eni-lowo yii mu ki ise ti o le gbani ni akoko pupo,  di sise ni kia, ati wi pe o mu ki wahahala din ku laaarin awon eniyan ti won n gbe ni agbegbe kan naa. Bi apeere: ise oko, ile kiko, owo yiya ati bee bee lo. 

Orisi ona ti a n gba ran ara wa lowo

(1)  Aaaro

(2)  Owe

(3)  Esusu

(4)  Ajo

(5)  Owo eke kiko/Sogun-dogoji

(6)  San-die-die

(7)  Fifi omo/nnkan ini duro