podcast
details
.com
Print
Share
Look for any podcast host, guest or anyone
Search
Showing episodes and shows of
Excellent Abiodun Adedeji
Shows
You Top Radio TV
MOJII RE! Ep46 - You Top Radio TV. Pelu Excellent Tripple A OMO YORUBA AJ'ORUKO BI OYINBO.. Akori: ODI ABO
The strongest fence you need to build are people. Those you give a helping hand to and those that rises through you are the strongest fence and brace for your ladder. MOJII RE!
2022-12-06
15 min
You Top Radio TV
Akojopo Iroyin lori- You Top Radio TV Pelu Omo Yoruba Aj'oruko Bi Oyinbo
E ma gbo iroyin ki e ba le ma mo bi o se nlo lawujo yin.
2022-12-05
12 min
You Top Radio TV
MOJII RE! Ep45. Pelu Excellent Tripple A -Omo Yoruba Aj'oruko Bi Oyinbo. /Akori: ORUKO. on YOU TOP RADIO TV
Your name is your link that is use in most cases to connect you to the place you are destined to be, therefore, protect it. MOJII RE
2022-12-05
14 min
You Top Radio TV
MOJII RE! Ep44 Pelu Excellent Tripple A- Omo Yoruba Aj'oruko Bi Oyinbo. 1/12/20222. Akori: OJUSE RE SI ARA RE. on YOU TOP RADIO TV
Bi o ti se wo inu Osu kejila Loni, mo fe ki o mo daju wipe Ojuse re to o ga ju si Ara re ni lati maa mu inu Ara re dun ni igba gbogbo. Osu yi a San fun wa ooo. MOJII RE
2022-12-01
15 min
You Top Radio TV
MOJII RE! Ep.43 - Pelu Excellent Tripple A- Omo Yoruba Aj'oruko Bi Oyinbo. Akori: Ja oju E. Lori: You Top Radio TV
Olubori ni O to o ba le bere ohun ti o fe se. Ati bere nkan lole, to eniyan ba to bere o ti Segun re niyen. MOJII RE.
2022-11-24
15 min
You Top Radio TV
MOJII RE! Ep. 42 Pelu Excellent Tripple A- Omo Yoruba Aj'oruko Bi Oyinbo. Akori: OLE NI MAJE KO MU E MOLE 2 . On You Top Radio TV
A nte siwaju Lori Akori ti a mba bo Lana, Ole Ni IJAFARA, maje ko mu e mole. Fun Ipolowo lori eto yi. 08164227860, 09157564995.
2022-11-23
15 min
You Top Radio TV
MOJII RE! Ep41 Pelu Excellent Tripple A - Omo Yoruba Aj'oruko Bi Oyinbo. Akori: OLE NI, MA JE KO MU E MOLE // On You Top Radio TV
Oro Yoruba Kan so wipe, Ijafara lewu, idi niyi ti Akori eto MOJII RE toni Fi da lori "OLE NI, MAJE KO MU O MOLE." Tani Ole Yi? Bawo lose no agbara to? Ona wo lo ngba se ise re? Awon ibeere Yi ati Awon miran ni eto yi ma se alaye re fun wa ni yekeyeke. MOJII RE!
2022-11-22
15 min
You Top Radio TV
MOJII RE//Episode 40 // Pelu Excellent Tripple A -Omo Yoruba Aj'oruko Bi Oyinbo// Topic: PACKAGING On You Top Radio TV
Ma fi owo yepere my Ara re, nitori bi onigba ba se pe igba e, ni Awon Aniyan se maa ba pe. MOJII RE?!
2022-11-21
15 min
You Top Radio TV
MOJII RE! Ep39 // Akori: KO SI ANFANI ELEEKEJI FUN // Pelu Excellent Tripple A- Omo Yoruba Aj'oruko Bi Oyinbo. // 3/11/2022
Kosi Anfaani eleekeji fun (No second chance for it) Lori eto MOJII RE loni adura mi fun wa ni wipe A o mi siwa Wu lase Olodumare. MOJII RE.
2022-11-03
15 min
You Top Radio TV
MOJII RE // Ep. 38 // Akori: TALO JEBI? Pelu Excellent Tripple A- Omo Yoruba Aj'oruko Bi Oyinbo //02/11/2022
Talo Jebi? We Awon Obi ni abi Awon Omo ta nbi Loni? E ma ba mi kalo lori eto MOJII RE fun toni Ojo keji Osu Kookanla odun 2022.MOJII RE!09157564995, 08164227860TWITTER: @adeomoyotubaINSTAGRAM: @excellent_ajorukobioyinbo
2022-11-02
15 min