podcast
details
.com
Print
Share
Look for any podcast host, guest or anyone
Search
Showing episodes and shows of
Olusam_Babs
Shows
Olusam_Babs
Yoruba Proverb Analysis 1
This Episode analysed an adage of the Yorubas on problem solving. --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2024-06-22
01 min
Olusam_Babs
Ẹ̀dá Ọwọ́ Ọlọ́run (Ẹyẹlé)
Tòòòò, fọ́nrán àkọ́kọ́ fétò tá a pè ní "Ẹ̀dá Ọwọ́ Ọlọ́run" rèé tí a pàkọlé rẹ̀ ní 'Ẹyẹlẹ́'. Ẹ tẹ́tí gbáwọn ohun kàyéfì nípa Ẹ̀dá Ẹyẹlé, ẹ sàfikún àwọn ohun tẹ́yin ín mọ̀ nípa ẹ̀dá ọ̀hún lórí èyíkéyìí ojúpòó ìkànnì ìbánidọ́rẹ̀ẹ́ wa, bẹ́ẹ̀ ni k'ẹ́ ẹ sì fi sọwọ́ sáwọn olólùfẹ́ẹ yín, ká le jọ bomi Ọgbọ́n mu nínú ìhùwàsí Ẹ̀dá Ọwọ́ Ọlọ́run tí a mọ̀ sí 'Ẹyẹlé'. E máa rántí pé, Ó gbọgbọ́n o, bẹ́ẹ̀, ló gbẹ̀sọ̀. --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2022-07-01
02 min
Olusam_Babs
Idije Dibo
Election Matters --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2022-02-23
00 min
Olusam_Babs
Májẹ̀mú Òbí
This is to remind you of your promises to your parents during the festive seasons. --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2022-02-16
00 min
Olusam_Babs
Valentine's Day Celebration
Be careful of the season to avoid the treason. --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2022-02-14
00 min
Olusam_Babs
Ayé Gbẹgẹ́
The world is getting deadlier, be security conscious. --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2022-02-11
00 min
Olusam_Babs
IṢẸ́ RERE
This talks about what kind of work you should choose as career or occupation. --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2022-02-09
00 min
Olusam_Babs
IGI ELÉSO
This episode explains how important your personal development must be to you. --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2022-02-07
00 min
Olusam_Babs
ÈÉFÍN NÌWÀ
Ọ̀pọ̀ ènìyàn ló ní ìwà ipá ní kọ̀rọ̀ tí a kò gbọdọ̀ bá lọ́wọ́ wọn. Irú Ìgbésẹ̀ wo wá ni wọn yóò gbé? Ẹ tẹ́tí sí ọ̀rọ̀ Ọgbọ́n àti Ẹ̀sọ̀ yìí --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2022-01-18
01 min
Olusam_Babs
TA LÓ NI ÀKÓKÒ RẸ GAN-AN?
This talks about owing your time as an individual to enhance a better future. --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2021-11-09
05 min
Olusam_Babs
Orúkọ Àwọn Ẹyẹ Lédè Gẹ̀ẹ́sì àti Èdè Yorùbá
Ẹ̀kọ́ yìí dá lórí í orúkọ tí Ẹ̀yà Yorùbá ń pe Ẹyẹ kọ̀ọ̀kan àti ohun tí à ń pè wọ́n lédè Gẹ̀ẹ́sì. --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2020-08-27
14 min
Olusam_Babs
Orúkọ Àwọn Ẹranko lédè Gẹ̀ẹ́sì àti Yorùbá
Ẹ̀kọ́ yìí wà láti rán àwọn ènìyàn lọ́wọ́ lórí orúkọ ẹranko lédè Gẹ̀ẹ́sì àti Èdè Abínibí wa tí ṣe Yorùbá. --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2020-08-19
13 min
Olusam_Babs
ÀMÌ OHÙN II
Ìtẹ̀síwájú ẹ̀kọ́ lórí i Àmì Ohùn --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2020-08-02
12 min
Olusam_Babs
Àmì Ohùn
Ẹ̀kọ́ nípa Àmì àti Ìró Ohùn Èdè Yorùbá --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2020-07-20
11 min
Olusam_Babs
SÍLÉBÙ
Ọ̀kan pàtàkì nínú Ìṣẹ̀dá Ọ̀rọ̀ lédè Yorùbá --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2020-07-12
16 min
Olusam_Babs
ÌYÀTỌ̀ ÀṢÀ ÀTI Ẹ̀SÌN
Ọ̀pọ̀ ènìyàn ló ń fojú ẹ̀sìn wo àṣà, ǹjẹ́ bẹ́ẹ̀ ló rí? --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2020-07-05
10 min
Olusam_Babs
Ìró Kọ́ńsónáǹtì Èdè Yorùbá
Ìtẹ̀síwájú lórí ẹ̀kọ́ Álífábẹ́ẹ̀tì Èdè Yorùbá --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2020-06-28
09 min
Olusam_Babs
Ìró Álífábẹ́ẹ̀tì Èdè Yorùbá
A ṣe àgbéyèwò Ìró Fáwẹ̀lì Ède Yorùbá nínú ẹ̀kọ́ yìí......... --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2020-06-21
10 min
Olusam_Babs
Álífábẹ́ẹ̀tì Èdè Yorùbá
Ẹ̀kọ́ yìí dá lórí í Álífábẹ́ẹ̀tì Èdè Yorùbá eléyìí tó jẹ́ àkàsọ̀ pàtàkì nínú ẹ̀kọ́ ọ mọ̀-ọ́n kọ mọ̀-ọ́n kà. Bí wọ́n bá bi ọ́ gẹ́gẹ́ bí i akẹ́kọ̀ọ́ èdè Yorùbá, o gbọ́dọ̀ mọ̀ pé; Lẹ́tà Márùn-úndínlọ́gbọ̀n ló parapọ̀ di Álífábẹ́ẹ̀tì Èdè Yorùbá. Báwo ló ṣe jẹ́? Ẹ jẹ́ kí á tẹ́tí gbọ́ ọ --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2020-06-14
14 min
Olusam_Babs
Ìfáàrà
Èyí ni ìfáàrà sí àwọn ohun tí ẹ ó ní àǹfààní láti máa gbọ́ lórí ìkànnì yí. --- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2020-06-10
00 min
Olusam_Babs
Olusam_Babs (Trailer)
--- Send in a voice message: https://podcasters.spotify.com/pod/show/aru00e1ku00f9nrin-olu00fa/message
2020-06-10
00 min